Eroja:
(1)Ewe isin gbigbe mejila
(2)Ewe ogbo gbigbe mejila
(3)Apo meji abo tuntun eyoKan
(4)Alagba totiku metta
(5)igbo mimu ekiri metta
(6)Ewe ola gbigbe mejila
(7)Ose dudu topo die
(8)Ike funfun kekere tabi ewe èko
Sisere:A o gun gbogbo eroja yii papo,taba wa gun tan,a o wa ko sinu Ike funfun tabi inu ewe èko,leyii taba ko si ibikan tan,a o wa lo gbe si igun iyara Kan fun ojo metta,leyin ojo metta,o di lilo.
Lilore:Toba di ale[night]A o bu die ninu ose yii,a o da sinu apo nla Kan,Toba di ojo keji,a o ti ba owo ni inu apo naa,owo naa koni ju #500,000 Tested and okay
