ASEJE OWO
Ewe omisinmisin
Ewe aje
Ewe sinkirinmidin
Ewe sawerepepe
Ao lowonpo mo iyere
Ao wa eyin ororo meje
Ao se jina lechin igbati o ba jina ao bo sinu isasun ao da awon eroja talo lelori ao fi epo si
Ati iyo, ao fi iyere osun tefa osa meji ….
Ohunree:-
Akeroro
Alaroro
Alasasawoja
Arinrin gberegbere wo arin ilu lo polowo aje tantan,
Aduro lorita gbon tete tifigba ire lowo onire sebi akeroro loruko tanpe ifa alaroro loruko tanpe esu odara,
Alasasa woja ti nrinrin gberegbere wo arin ilu lo
Ti polowo aje tantan loruko eyin iyami osoronga aje , kiema duro lorita gba ire owo temi l-l
Eni nitori kini mose npeyin moni nitori aini owo lowo, moni mofe mani egbegberun lona egbegberun, lati oni yi lo eni odi dandan kin lowo egbegberun lona egbegberun, eni nitori enito obati mo oruko yin eo sokale wa silekun AJE fun emi l-l timo oruko yin, kie sokale wa silekun aje fun emi l-l, ki nba won fi owo se gbogbo nti aye nfowo se laiye,
Nitori mofe kole , mofe ra oko, mofe dokowo, moso fe losi olu oba , kie ma se dina mo mi mo lailai, moti sefa aje loni oo awerepepe kiolo pe alaje temi wa fun mi oo,
Sinikinimini ki moni koto koni mora, ile aiye mi ti ladun latoni yii lo adukan ni ewe olomisinmisin ma ndun kan won, iyere lomo bami yii won lokan pada kiwon o wa fi ire aje temi wa mi wa , iyere osun majeki ire aje temi o sun lowo okunrin lowo obinrin
Osa meji lo bamii sale sa ona owo nlanla wa
Awa koje pata pata biabati nje lowo
Beni ao ma sope atokunrin ati obinrin lohun ke eyin gege ki tokurin tobinrin o ma fi ire aje kemi gege
Odaju ooo
