Turari isora

ASALAM ALAYKUN WARAMONTU LAHI WABARAKATUHU

TURARI ISORA LOWO AWON AJE ATI AWON EMI BURUKU TODAJU SAKA

AO HAN TABATIYADA (66) KULI ALAHU (66) AYATU IRIS(66) SI OJU WALAHA DUDU AO WA FI OMI OKUN TABI OMI SAMSAM FO AO DA SI
IBIKAN
GARIRE=ewe ajeobale ewe lobotuje pupa eku eliri okunrun eba ona epo obo epo iginla odidi atare kan ao jopo ao dasinu hantu na ao tu lofinda bintu sudan odidi meta si lofinda danduala odidi meta si ao ropo dada ao ma fi sara jade
HUN WALAHI ATARI AJANAKU NI KISE ERU OMODE
TI AWON AJE TABI AWON ENI IBI BAGBORUN RE LARA WA LASAN WALAHI WON YIO MA SALONI
ISE YII LE GAN NI KODA GBOGBO AWON EMI AIRI TOBURU WON YIO MASA FUN WA NI

MOLO KOSISE IRO LONJEBE
EYAN PUPO LELO NIBI TURARI NA

WALAHI KOSI INTI LEBO LOGUN NI ABI AWON PASTOR NI TI KOSI LOWO AWA MUSULUMI NA EDAKUN EMA JE KAMA WA IRAN LOWO LOSI ODO WON MON
EJE KAMA SOFUN AWON KEFERI WIPE(LAKUNDINUKUN WALIYADINI)

MASALAM!!!!!!!


Leave a comment

Design a site like this with WordPress.com
Get started