(ADUAHU SEIFI LIMUSILIMU)ADUA NI IDA MUSULUMI
IWO OMO IYAMI NINU ISLAM DAKUN MAWA IRANLOWO LOSI ODO ELOMIRAN AYAFI ODO OLOHUN OBA
IWO KAN GBIYANJU ADUA YI WO KOWA RI WIPE ADUA NIGBA AGBARA KO
GBOGBO IWO TI OHUN WA OGUN TI OMA FILU JIBITI O BETTER KO STOP RE KO TERA MON ISE APARE
WALAHI TI OBA GBIYANJU ADURA YI WA RI WIPE OMA GBA ISE GIDI TI OSI RI OWO NIBE JU JIBITI TI OUN LU LO
ABO ORO TO FUN OMOLUABI TOBA DENURE YIO DI ODIDI
ADUA IRANLOWO ATI ARISIKI LODO OLOHUN LORI EYIKEYI ISE TI ABANSE
nafila merin salamo meji lori iduro kokan fatia kan kuliuwalahu merin lahilahilalahu mokanla lori iduro kokan leyin igba ti aba salamon ao wa ka awon adua yii
astagafirulahi 303 alhamdulilahi 303 lahilailalahu 505 lehin na ni ao wa toro iru arisiki iranlowo ti abafe lodo olohun aniyan eyo kan soso ni ama toro kise wipe atun ma toro omi ran ao masebe fun ojo meje tabi 21 days tabi iye ojo ti oba wuwa olohun ni lati fun wa ni eyi ti aba toro na odaju
