IPESE ASINA AWON AGBALAGBA:Ekuru funfun mefa
- A o ko sinu awo IPESE titun
-A o tu oyin le ekuru yen lori
-A o bu iyo die sinu iyere osun
-A o fi te ifa osameji soju kan
-A pe gbolohun re si
-A o wa da sori ekuru,a o gbelo sori ta meta lale.
GBOLOHUN RE:Asurenipa abara funfun gboo,ole onibuso loja,ti ole ba ni buso loja ni iba ti sare Aje, adi fa fun abimbola ti somo won nilu awon aje,oni oun yio ba ilu awon aleye je,awon eleye wipe kilode to fife ba ibugbe awon je.oni oun ori je oun ori mu oun ori na on ori lo.awon eleye wipe kilo fe ki awon ose fun.oloun fe di onire gbogbo.awon eleyeni kolo toju ekuru mefa,oyingan, iyo.ki o wa te ni osameji.ki o ran itan ifa yi si,kio gbe pade awon ni orita meta.awon eleye o so di onire gbogbo.ipese yi na ni emi L omo L wa gbe wa yio,ewa so mi di onire gbogbo.a o se adura si daada a o si gbe lo si orita meta. Hmmmm ipese yi daju pupo gbiyanju ko Dan wo kofun ile labo
👍 LIKE
👍 COMMENTS
👍 SHARE
👍FOLLOW DIS PAGE
